Yoruba Poem

Words
58
Reading
1 min
9y
Listen to this post
~1 min

DÈRÈ OLÓLÙFẸ́ Ẹ̀MÍ AÌRÍ

Ìtùnú though ẹ̀mí aìrí ni ìwọ
Mo mọ̀ wípé nkò lèrí ojú rẹ
Sùgbọ́n ìṣèsi rẹ ti mú mi mọ́lè bí ẹ̀mú

Dèrè though ẹ̀mí aìrí ni mí
Èmi Ìtùnú náà ni ọkàn
Owùmí dé òde ìsálú ọ̀run
Dèrè má se ìlérí nítorí yóò di ìmùlẹ̀
Sùgbọ́n,Dèrè mọ̀ wípé iyanrìn òkun ti
Òkun níse.

Yoruba Poem | Ecency